My Jesus,
I believe that You
are present in the Most Holy Sacrament.
I love You above all things,
and I desire to receive You into my soul.
Since I cannot at this moment receive You sacramentally now,
come at least spiritually into my heart.
I embrace You as if You were already there and unite myself wholly to You. Never permit me to be separated from You.
Amen.
ISE ARA-OLUWA TI EMI TI ALFQNSU MIMO
Jesu mi,
mo gbagbo pe
Iwo wa ninu Sakramenti mimk. Mo ni fe re ju ohun gbogbo lo,
mo si se tan lati gba o sinu okan mi.
Sugbon bi n ko se le gba o ninu sakramenti nisisiyi,
je ki n le gba o ni emi sinu okan mi.
Mo ro mo o bi o se wa ninu okan mi, mo darapo mo o
ma se je ki n yapa kuro lodo re. Amin.